Check Out Nigeria’s National Anthem in Yoruba Language

1 Min Read

Can you sing the National Anthem in Yoruba language?

VERSE 1
Dide eyin ara
Waka je ipe Naijiria
K’a fife sin ‘le wa
Pel’okun at’igbagbo
Kise awon akoni wa,
ko mase ja s’asan
K’a sin t’okan tara
Ile t’ominira,at’al
aafia
So d’okan

VERSE 2
Olorun Eleda
To ipa ona wa
F’ona han asaaju
K’odo wa m’otito
K’ododo at’ife po sii
K’aye won je pipe
So won d’eni giga
K’alafia oun eto le
Joba ni ‘le wa

THE PLEDGE
Mo se ileri fun Orile-Ede mi Naijiria,
Lati je olododo, eniti o see f’okan tan
Ati olotito eniyan
Lati sin in pelu gbogbo agbara mi,
Lati sa ipa mi gbogbo fun isokan re
Ati lati gbe e ga fun iyi ati ogo re.
Ki Olorun ran mi l’owo

2283061_12_jpegd077e4317cde1e70737c7d5616929159

Share this Article